Gomina AbdulRahman AbdulRazaq t'ipinlẹ Kwara ti bu ọwọ lu Pasitọ Timothy Oluwagbemiga Akangbe gẹgẹ bi amugbalẹgbẹẹ pataki rẹ lori ọrọ to ni i ṣe pẹlu ẹsin Kristẹẹni
Akangbe, gẹgẹ bi iroyin to tẹ wa lọwọ ṣe sọ, oun lo rọpo Pasitọ S. O. Adedayọ, ẹni jade laye laipẹ yii.
Ọkan pataki lara awọn ọmọ ẹgbẹ onigbagbọ, iyẹn Christian Association of Nigeria, CAN ni Akangbe jẹ, to si ni iwe ẹri nipa ọrọ ẹsin Kristẹẹni ni fasiti ilu Ibadan.
No comments:
Post a Comment