Ijọba ipinlẹ Kwara labẹ Gomina AbdulRahman AbdulRazaq ti gba gbogbo awọn agbaṣẹṣe lamọran lati jara mọ iṣẹ akanṣe ti wọn gbe le wọn lọwọ, lojuna lati tete pari wọn, ko si si lilo fun igbadun araalu.
Yatọ si eyi, ijọba Kwara tun gba gbogbo awọn araalu, paapaa awọn awakọ lati ṣe suuru gidigidi lawọn opopona, iyẹn bi akanṣe iṣẹ idagbasoke opopona ṣe n lọ kaakiri lọwọ.
Wọn jẹ ko di mimọ pe awọn ohun amuyẹ bii ilana lati wa ọkọ loju popona lọsan ati loru ni ijọba ti pese silẹ, ki wọn si tẹle awọn ilana ọhun.
Bakan naa nijọba tun jẹ ko ye araalu wi pe awọn oṣiṣẹ oju popona ti yoo maa dari ọkọ lọtun losi yoo wa nita lati dari ọkọ, fun idi eyi, awọn eeyan ko gbọdọ tapa si idari wọn.
Lara awọn opopona ti akanṣe iṣẹ idagbasoke opopona yoo ti maa lọ ni Osi-Obbo Aiyegunle, Ilesha Baruba Gwanara, Afara oloke ti General Tunde Idiagbon ati Yebumot – layipo (Roundabout) Adeta – Mount Carmel.
Awọn opopona ti yoo bẹrẹ lọsẹ to n bọ ni:
i. Reconstruction of Adeta Roundabout - Pakata Roundabout, Ilorin
ii. Rehabilitation of Oja Roundabout - Pakata Roundabout, Ilorin
iii. Construction of Oloje - Ita Aman Madi Road, Ilorin
iv. Tanke Oke Odo Ring Road 1.8km Ilorin
v. Construction of Ballah Township Road (Rehabilitation of Eyenkorin to Ballah 6.2Km)
vi. Construction of General Hospital Road - Otte
vii. Construction of Ora Township Road
viii. Secretariat road to New Market Lafiagi Township, Lafiagi
ix. Tsaragi Township Road Edu
x. Rehabilitation of Iyana Shonga to Shonga Road, Shonga
xi. Construction of Tsuba – central School, lade Patigi
xii. Construction of Oloje road linking Balode
xiii. Construction of Coca Cola – Palace Road, Jebba
xiv. Construction of Lanwa Township
xv. Construction of Oloru Township Road
xvi. Bani Township Road
xvii. Construction of Okuta Central Mosque Junction - Emirs Palace - Sakiyara
xviii. Construction of Saint Clairs Junction Offa Ikotun Road
xix. Oko – Idofin – Igbana Road Rehabilitation
xx. Construction of Oke Oyi Township Road
xxi. Construction of (2x12.5) span Bridge along Bukka-Adena Road Kaiama
No comments:
Post a Comment