Gomina AbdulRahman AbdulRazaq ti ipinlẹ Kwara ti yan igbimọ iṣakoso fun ileeṣẹ igbohunsafẹfẹ ti Redio Kwara, eyi ti alaga igbimọ ọhun jẹ ogbontarigi akọroyin, Ọgbẹni Kayọde Adeyipo.
Adeyipo ni alakoso ẹka to n ri sọrọ iroyin ati bo ṣe n lọ nileeṣẹ redio naa tẹlẹ.
Lara awọn ọmọ igbimọ naa ni Muhammad Buhari Jimọh; Hajia Aisha Muhammad; Ọmọwe (Arabinrin) Amina S. Ahmẹd; Ọnarebu Mary Ẹbun Oyelẹyẹ; Hajia Bọlajoko Jumọkẹ Bello; ati Onimọ-ẹrọ Dele Aje.
No comments:
Post a Comment