AbdulRazaq, Sanwo-Olu, Fayẹmi, Ọṣinbajo pade l'Abuja (Fọto) - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Sunday, February 27, 2022

AbdulRazaq, Sanwo-Olu, Fayẹmi, Ọṣinbajo pade l'Abuja (Fọto)


L'Ọjọru, Wẹsidee, to kọja yii ni Gomina ipinlẹ Kwara AbdulRahman AbdulRazaq, atawọn gomina ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress meloo kan pade nile agbara to wa nilu Abuja, iyẹn Aso Rock.
 
Igbakeji aarẹ, Ọjọgbọn Yẹmi Ọṣinbajo naa wa nibi ipade yii.
 
Lara awọn to tun wa nibẹ ni, Gomina ipinlẹ Eko, Babajide Sanwo-Olu; ipinlẹ Ekiti, Kayọde Fayẹmi atawọn mi in.
 
Fọto naa ree...





No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI