Pupọ awọn to ri gbajugbaja oṣere tiata nni, Mercy Aigbe pẹlu ọmu rẹ mejeeji to ko sita gbangba lori ikanni ayelujara lonii, ọjọ Abamẹta, Satide ti ko nii ṣe ni kayeefi.
Kii ṣe tuntun mọ pe gbogbo ọjọ kin-ni-in, oṣu kin-ni-in, ọdun ni ayẹyẹ ọjọ ibi Mercy Aigbe ti ko si nile ọkọ kankan lakooko yii.
Aṣọ ti Mercy Aigbe, iya ọlọmọ meji naa wọ lo fẹẹ le ṣi ihooho rẹ silẹ, bo tilẹ jẹ pe idaji ara rẹ lo wa nita.
Diẹ ree lara fọto naa:
No comments:
Post a Comment