Ọpẹ́ o! AbdulRazaq bu ọwọ́ lu owó oṣù Disẹmba fáwọn òṣìṣẹ́ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, December 20, 2021

Ọpẹ́ o! AbdulRazaq bu ọwọ́ lu owó oṣù Disẹmba fáwọn òṣìṣẹ́


Inu idunnu ati ayọ lawọn oṣiṣẹ ijọba kaakiri ipinlẹ Kwara wa bayii, pẹlu bi Gomina AbdulRahman AbdulRazaq ṣe bu ọwọ lu owo oṣu kejila, ọdun 2021 fun gbogbo wọn.
 
AWIKONKO gbọ pe ko si nnkan meji to jẹ ki Gomina AbudulRazaq bu ọwọ lu owo oṣu yii, iyẹn disẹmba fun awọn oṣiṣẹ, bi ko ṣe ti ayẹyẹ ọdun Keresimesi ati ọdun tuntun to n bọ lọna, ki awọn oṣiṣẹ le ri owo fi ṣe ọdun wọn lai banujẹ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI