Olówu tìlú Òwu Abẹ́òkúta, Ọba Adégbóyèga Dòsùnmú waja - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, December 13, 2021

Olówu tìlú Òwu Abẹ́òkúta, Ọba Adégbóyèga Dòsùnmú waja


Olowu tilu Owu nilu Abẹokuta, Ọba Adegboyega Dosunmu, Amọroro keji ti waja, o ti lọ bawọn baba nla rẹ lajule ọrun.

Ana, tii ṣe Aiku, Sannde la gbọ pe kabiyesi jade laye.

Ọdun 2005 ni wọn fi Kabiyesi jẹ, labẹ iṣakoso Gomina Gbenga Daniel.

Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ iroyin naa n bọ laipẹ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI