Ohun tó bà mí lọ́kàn jẹ́ - Ibrahim Chatta sọ̀rọ̀ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, December 20, 2021

Ohun tó bà mí lọ́kàn jẹ́ - Ibrahim Chatta sọ̀rọ̀


Gbajugbaja oṣere tiata nni, Ibrahim Abiọdun Chatta ti sọrọ jade lonii nipa ohun to ba a lọkan jẹ julọ, eyi to mu ko pariwo sita lori ikanni ayelujara.

Ninu fọnran kan ti Ibrahim Chatta gbe jade sita lo ti dupẹ lọwọ awọn ololufẹ rẹ ti wọn pe e, ti wọn si gba a lamọran lati ṣe ọkan akin.

Fọnran naa ree


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI