Ọọ̀ni Ilé-Ifẹ̀, Ọba Ògúnwùsì gboyè Ọ̀mọ̀wé ní fásitì ABUAD - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Friday, November 26, 2021

demo-image

Ọọ̀ni Ilé-Ifẹ̀, Ọba Ògúnwùsì gboyè Ọ̀mọ̀wé ní fásitì ABUAD

IMG_ORG_1637921134297

Ọọni Ile-Ifẹ, Ọba Adeyẹye Ẹnitan Ogunwusi naa ti wa lara awọn agba ọba alaye ti wọn gboye Ọmọwe bayii, pẹlu fasiti Afẹ Babalọla to wa nilu Ado-Ekiti, ipinlẹ Ekiti ṣe fi oye Ọmọwe daa lọla.

Gẹgẹ bi a ṣe gbọ, ọjọ Aiku, Sannde to kọja yii ni Ọọni gba iwe-ẹri oye naa, iyẹn Degree of Doctor of Letters, Honoris Causa.

Nibi ayẹyẹ ọdun mejila ti wọn da fasiti naa silẹ, ati ikẹkọọ-gboye ọdun kẹsan-an ni Ọọni Ile-Ifẹ ti fi itan tuntun balẹ.

IMG_ORG_1637921145154

IMG_ORG_1637921145263

IMG_ORG_1637921145356

IMG_ORG_1637921145449

IMG_ORG_1637921145064


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI

Contact Form

Name

Email *

Message *