Ọkunrin ẹni ọdun mẹtadinlaadọta kan, ti wọn ju sẹwọn ọdun mẹẹdogun lori ẹsun wi pe o fipa ba ọmọ ọrẹ rẹ, ọmọ ọdun mẹfa laṣepọ, iyẹn Selwyn Lancaster ti pe ẹjọ kotẹmilọrun bayii.
AWIKONKO gbọ pe ọdun 2019, ni wọn ju Lancaster sẹwọn naa lori ẹsun meji ọtọọtọ to nii ṣe pẹlu ifipabanilopọ.
No comments:
Post a Comment