Ọjọgbọn Banji lonii, ọjọ Iṣẹgun, Tusidee ti sọ pe oun ti kọwe fipo silẹ gẹgẹ bi alaga ẹgbẹ Ilana Ọmọ Oodua, iyẹn ẹgbẹ to n ri si bi atunto yoo ṣe wa kaakiri ilẹ Yoruba.
Gẹgẹ bi iroyin to tẹ AWIKONKO lọwọ ṣe sọ, wọn ni ko si nnkan meji to jẹ ki Banji Akintoye fipo naa silẹ, bi ko ṣe bawọn agba Yoruba kan ko ṣe ni afojusun kan naa pẹlu ohun ti ẹgbẹ Ilana Ọmọ Oodua duro fun.
Akintoye, ẹni to tun jẹ alaga fun ẹgbẹ Nigerian Indigenous Nationalities Alliance for Self-Determination (NINAS), naa sọ pe oun ko le maa ba bayii lọ, paapaa julọ bi ẹnu awọn agba Yoruba ko ṣe ko.
Yatọ si eyi, wọn ni awọn ti gbe ẹgbẹ Ilana Ọmọ Oodua kuro labẹ ẹgbẹ NINAS to so gbogbo awọn ẹgbẹ to n gbenu sọ fun awọn oriṣiriṣi ẹya lorilẹ-ede Naijiria papọ.
Ninu atẹjade ti ẹgbẹ naa gbe jade, Akintoye at'awọn aṣaaju mẹrinlelogoji ninu ẹgbẹ Ilana Ọmọ Oodua naa sọ pe awọn ko le tẹsiwaju mọ.
Awọn to fọwọ siwe naa ni:
1. Prof. Banji Akintoye - Alana of Ilana Omo Oodua Worldwide.
2. Professor Wale Adeniran
3. Dr. Kayode Akinwande
4. Engr. Muda Ogunsola
5. Dr. Gbenga Adeyeye
6. Mr. Maxwell Adeleye
7. Dr. Adejuwon Akinsola
8. Pastor Ayodele Praise - Ekiti StaCoordinator, Ilana Omo Oodua
9. Prince Ade Adefioye - Lagos State Coordinator, Ilana Omo Oodua
10. Mr. Adekanola Desmond - Mobilisation Unit
11. Omo Oba Kazeem Onikeke - Oyo State Coordinator, Ilana Omo Oodua Worldwide
12. Comrade Bankole Adeniyi - Ondo State Coordinator
13. Princess Tanimowo Okusaga - Women Wing
14. Ms Egbinlade Adebola - Ilana Omo Oodua, Canada Chapter
16. Mr. Seun Aribilola - Coordinator, Ilana Omo Oodua, United States of America
17. Chief Jimoh Olawale Taofeeq - Ogun State Coordinator, Ilana Omo Oodua
18. Ms Funmi Soyemi - Coordinator, Ilana Omo Oodua, Republic of Ireland
19. Sheik Aduranigba Chief Imam - Ilana Omo Oodua Elders Advisory Council
20. Alhaji Ali Oyedeji- Chairman, Ilana Omo Oodua Elders Advisory Council
21. Otunba Tomi Koledoye - Ilana Omo Oodua Elders Advisory Council
22. Madam Judith Richard Kila - Ilana Omo Oodua United Kingdom
23. Dr. Chief Sola Oni - Coordinator, Ilana Omo Oodua, United Kingdom
24. Mr. Ademola Abidoye - Ilana Omo Oodua, United Kingdom
25. Prof. Ade Kukoyi- Chairman, Ilana Omo Oodua Think-Tank Council
26. Mr. Bolarinwa Ade - Ilana Omo Oodua Germany
27. Prince Adekunle Adelakun - Ilana Omo Oodua Homeland Council
28. Mr. Wasiu Iyanda - Ilana Omo Oodua Youth Wing
29. Mr. Elisha Ademoyegun - Ilana Omo Oodua Youth Wing
30. Ms Bolanle Cole - United States
31. Mr. Emmanuel Akanbi - Canada
32. Mr. Uthman Ikosiola - United States
33. Mr. Isiah Teju - Canada
34. Chief Mrs Ronke Okusanya
35. Dr. Funso Famuyiwa
36. Mrs Busola Akintoye
37. Oladapo Kayode, Esq
38. Ms Tosin Adeleye
39. Com. Deji Adebayo - Ilana Omo Oodua IT Unit
40. Com. Femi Oluwajuyitan - Ilana Omo Oodua New Media Unit
41. Mr. Ibrahim Hammed - Ilana Omo Oodua Tech Unit
42. Ms Precious Olusola Adesola - United Kingdom
43. Mr. Telita Sule - Ilana Omo Oodua Research Unit
44. Dr. Tunde Amusat - Ilana Omo Oodua Worldwide Administrative Secretary
45. Mr. Oluwole Fatunde - Ilana Omo Oodua United Kingdom
:
:
:
:
;
Cc; Facebook page #ilanaomoodua
No comments:
Post a Comment