Alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC ní Kwara ṣàbẹ̀wò sí Tinubu l'Abùjá - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Friday, November 12, 2021

Alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC ní Kwara ṣàbẹ̀wò sí Tinubu l'Abùjá


L'Ọjọbọ, Tọside ana ni alaga ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress, APC nipinlẹ Kwara, Ọmọọba Sunday Fagbemi ṣabẹwo si Aṣiwaju Bọla Ahmed Tinubu nile rẹ to wa nilu Abuja.

AWIKONKO gbọ pe Ọmọọba Fagbemi ati igbekeji rẹ, to fi mọ alaga ẹgbẹ naa ni aarin gbungbun ẹkun Guusu ipinlẹ naa, Ọnọrebu Ọlabanji Ọlayẹmi ni wọn jọ lọ ṣe abẹwo ọhun.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI