Ẹgbẹ kan ti wọn pe ara wọn ni Southern and Middle-Belt Alliance (SaMBA), ti rọ Aarẹ Muhammadu Buhari atawọn gomina ilẹ Guusu-Ila-Oorun (South-Eastern) orilẹ-ede yii lati foju awọn to n ṣagbatẹru awọn agbebọn, ki wọn si mu wọn balẹ lẹsẹkẹsẹ.
Ninu atẹjade ti agbẹnusọ ẹgbẹ naa, Ọmọọba Rwang Pam Jnr. fi sita lonii, ọjọ Aje, Mọnde lo ti sọ pe ki Buhari gbe igbesẹ lati gbogun ti iwa ibajẹ awọn agbebọn to n fojoojumọ pọ si, paapaa nipinlẹ Anambra, ati gbogbo agbegbe Guusu Ila-Oorun naa.
No comments:
Post a Comment