Mi ò gbé àpótí ìbò gómìnà láti kọ́ ilé tàbí ra mọ́tò tuntun - AbdulRazaq - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, October 28, 2021

Mi ò gbé àpótí ìbò gómìnà láti kọ́ ilé tàbí ra mọ́tò tuntun - AbdulRazaq


Gomina ipinlẹ Kwara, AbdulRahman AbdulRazaq lonii, Ọjọbọ, Tọside ti jẹ ko ye gbogbo awọn eeyan kaakiri agbaye, paapaa awọn ọmọ ati olugbe ipinlẹ naa wi pe oun ko gbe apoti ibo gomina lati kọ ile tuntun tabi ra mọto tuntun.

AbdulRazaq sọ pe idi pataki toun fi gbe apoti lati jade du ipo gomina toun n ṣe lọwọ yii ni lati sin awọn araalu, koun si mu wọn kuro ninu okunkun bọ sinu imọlẹ ayeraye.

Siwaju sii lo tun sọ pe oun wa pẹlu ọkan to mọ, toun si nigbagbọ ninu Ọlọhun wi pe oun ko ni ja awọn araalu kulẹ ninu ipinnu oun.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI