Ìjọba mẹ̀kúnnù sọ ìgbà tí iṣẹ́ yóó parí lójú ọ̀nà Ilesa Baruba si Gwanara - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Tuesday, October 19, 2021

Ìjọba mẹ̀kúnnù sọ ìgbà tí iṣẹ́ yóó parí lójú ọ̀nà Ilesa Baruba si Gwanara


Ijọba ipinlẹ Kwara ti sọ pe oju ọna marosẹ Ileṣa Baruba si Gwanara to jẹ kilomita mẹtalelọgbọn nni ti wọn dawọ le yoo pari ki oṣu mẹrin akọkọ, ọdun 2022 too pari.
 
Wọn ni eyi yii jẹ ki igbokegbodo ọkọ loju ọna naa rọrun pupọ fawọn araalu, ti eto ọrọ aje yoo si tun rọrun ni rẹpẹtẹ.

AWIKONKO gbọ pe o ti pẹ ti awọn ijọba to kọja lọ ti pa atunṣe opopona naa ti, eyi to n fa ọwọ ọrọ aje sẹyin nipinlẹ naa, ṣugbọn ti ijọba to wa nita lakooko yii ti ṣeleri wi pe awọn yoo rii pe awọn araalu jẹ mudunmudun iṣejọba awaarawa.
 
Diẹ ree lara awọn fọto iṣẹ to n lọ lọwọ.
 





No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI