Gómìnà AbdulRazaq ṣàbẹ̀wò síbi ìmọ̀ ètò ayélujára, ICT Hub tí wọ́n n kọ́ lọ́wọ́ ní Kwara (Fọ́tò) - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, October 25, 2021

Gómìnà AbdulRazaq ṣàbẹ̀wò síbi ìmọ̀ ètò ayélujára, ICT Hub tí wọ́n n kọ́ lọ́wọ́ ní Kwara (Fọ́tò)

 
Gomina ipinlẹ Kwara, AbulRahman AbdulRazaq ti ṣabẹwo sibi imọ eto ayelujara, iyen ICT Hub ti wọn n kọ lọwọ lati mọ ibi ti iṣẹ de duro, ati eyi to ku.
 
Diẹ ree lara awọn fọto abẹwo naa:
 





No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI