Ìjà dópin! Amosun ṣàbẹ̀wò si Tinubu ní Lọndọnu (Fọ́tò) - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, September 2, 2021

Ìjà dópin! Amosun ṣàbẹ̀wò si Tinubu ní Lọndọnu (Fọ́tò)


Gomina ana nipinlẹ Ogun, Sẹnetọ Ibikunle Amosun ti ṣe abẹwo kara-o-le si Aṣiwaju ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress APC, Aṣiwaju Bọla Ahmed Tinubu nilu Lọndọnu.

Sẹnetọ Amosun, ẹni to n ṣoju Ààrin-gbùngbùn ipinlẹ Ogun, iyẹn Ogun Central nile igbimọ aṣofin agba l'Abuja wa lara awọn ti wọn ko tii yọju si Tinubu latigba to ti lọ gba itọju nilu Lọndọnu.

Diẹ ree lara awọn fọto bi abẹwo naa ṣe lọ si:





No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI