Gomina AbdulRahman AbdulRazaq tipinlẹ Kwara ti bu ọwọ lu atunṣe awọn opopona tuntun kaakiri ipinlẹ naa, lati mu irọrun ba igbokegbodo ọkọ.
Lara awọn ọna to nilo atunṣe, ti Gomina AbdulRazaq bu ọwọ lu pe ki iṣẹ bẹrẹ ni:
1. Ikorita Maraba - Ọja Ipata
2. Ikorita Chapel - Sanrab Tanke
3. Royal Shekinah - Garaaji Ọffa
4. Opopona High Court
5. Oju ọna Unity
6. Geri-Alimi - oju ọna Asa Dam
7. Challenge/Post Office
8. Oju ọna Taiwo
9. Opopona Kaduna
10. Oju ọna Oloje/Alore
11. Oju ọna Akerebiata
12. Oju ọna Alimi
13. Oju ọna Onikanga
14. Oju ọna Police
15. Oju ọna Ilofa
No comments:
Post a Comment