Lónìí, Ọjọ́rú, Wẹside, ọjọ kẹẹdọgbọn, oṣu kẹjọ ti a wa yii, nijọba ipinlẹ Kwara san owo oṣu kẹjọ fun gbogbo awọn oṣiṣẹ wọn patapata.
Gẹgẹ bi a ṣe gbọ, wọn ni ṣe lawọn oṣiṣẹ bẹrẹ sii ṣe adura lọpọlọpọ fun ijọba ipinlẹ naa nigba ti wọn bẹrẹ sii ri atẹjiṣẹ owo oṣu wọn to wọle lojiji.
Ẹkunrẹrẹ iroyin naa n bọ laipẹ.
No comments:
Post a Comment