Ijọba Kwara kọminu lori iku Alaaji Jooda - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, August 16, 2021

Ijọba Kwara kọminu lori iku Alaaji Jooda

Ijọba ipinlẹ Kwara ti kọminu lori iku agba alẹnulọrọ nni, Oloogbe Alaaji Ahmẹd Jooda ti jade laye lọsẹ to kọja yii.

Gomina AbdulRahman AbdulRazaq sọ pe ojiji ni iroyin iku naa ba oun, eyi to lo ba oun lọkan jẹ gidi ni kete toun gbọ.

O ni akikanju to ja fitafita fun orilẹ-ede Naijiria ni Alaaji Jooda nigba aye ẹ, to si ba awọn mọlẹbi rẹ kẹdun.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI