Kọmiṣanna fọrọ eto ikanisira-ẹni nipinlẹ Kwara, Arabinrin Ọlaitan Abọsẹde Buraimọh, ti gbe oṣuba kare fun ileeṣẹ redio tipinlẹ Kwara, lori ọna ti wọn n gba gbe iṣẹ iroyin ati igbohunsafẹfẹ larugẹ kaakiri agbaye.
Bẹẹ lo tun gbe oriyin fawọn oṣiṣẹ ileeṣẹ redio naa fun iṣẹ takuntakun ti wọn n ṣe lati maa fi bo ṣe n lọ laujọ to awọn araalu leti loore-koore.
has commended the management and staff of the state owned Nibi abẹwo ti kọmiṣanna naa ṣe lọ sileeṣẹ redio ọhun lo ti lu wọn lọgọ ẹnu.
No comments:
Post a Comment