Agbako nla! Haruna lu iyawo ẹgbọn rẹ pa nitori ọrọ ti ko to nnkan - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, August 5, 2021

Agbako nla! Haruna lu iyawo ẹgbọn rẹ pa nitori ọrọ ti ko to nnkan


Kani ki i ṣe pe awọn eeyan wa nibẹ ni, boya gendekunrin, ọmọ ọdun marundinlọgbọn kan, Danjuma Haruna ti wọn loo lu iyawo ẹgbọn rẹ pa ko ba ti na papa bora.
 
Haruna la gbọ pe o fun iyawo ẹgbọn, Zuwaira Bala ni ẹṣẹ nikun, tiyẹn si gbabẹ sọda sọrun alakeji lai duro dagbere fun ọkọ rẹ.
 
AWIKONKO gbọ pe ọrọ ti ko to nnkan lo ṣẹlẹ laaarin Haruna ati obinrin naa, to fi di pe awọn mejeeji bẹrẹ si i lu ara wọn. Alubami la gbọ pe Haruna fi iyawo ẹgbọn naa ṣe, ko to di pe o luu pa.
 
Abule kan ti wọn pe ni Gamatan to wa nijọba ibilẹ Miga, ipinlẹ Jigawa niṣẹlẹ ọhun ti waye lọjọ Iṣẹgun. Tusidee, ijẹta. Ọmọ ọdun marundinlọgbọn ni wọn pe Zuwaira Bala to lu pa
 
Ibi ti wọn ni Haruna ti fẹẹ na papa bora, lẹyin to lu obinrin naa pa la gbọ pe awọn eeyan ti sare mu silẹ, ti wọn si lọ fa a lẹ awọn ọlọpaa lọwọ. 
 
ASP Lawan Shiisu Adam to jẹ alukoro ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ naa fidi iṣẹlẹ yii mulẹ, o si ni Haruna ti wa lahamọ awọn.
 He said the incident happened on Tuesday evening after a misunderstanding between the suspect and his brother’s wife one Zuwaira Bala, 25-year-old at their compound in Gamatan village, Miga local Government.
 
Adam explained that the misunderstanding led to physical combat where the suspect allegedly used his leg and hit his brother’s wife at her stomach and as a result she fell down.
He said the victim was rushed to Jahun General Hospital for treatment and later confirmed dead by a medical doctor.
08103786922
The Police spokesman, however, said the suspect was arrested at Hadejia while trying to escape.
He said the Jigawa State Police Commissioner has directed that the case be transferred to the State SCID for discrete investigation.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI