Iba Abiọdun Ige Gani Adams, Aarẹ Ọna Kakanfo ilẹ Yoruba lo ti lọ ṣe abẹwo ibanikẹdun si gomina ipinlẹ Ogun, Ọmọọba Dapọ Abiọdun lori iku baba rẹ.
Ọjọ Aiku, Sannde ana ni Iba Gani Adams lọ ki Abiọdun nile ẹ to wa niluu Ipẹru, ipinlẹ Ogun.
NIPA IROYIN AWIKONKO
No comments:
Post a Comment