Awọn meji ti ẹ n wo yii ni wọn fẹsun kan wi pe wọn pa ọkan lara awọn ẹṣọ ologun orilẹ-ede yii, laipẹ yii.
Ohun ti a gbọ ni pe ẹka ileeṣẹ ologun ti Operation Delta Safe Headquarters to wa ni Igbogene, niluu Yenagoa, ipinlẹ Bayelsa, iyẹn Abbas Fatai lawọn mejeeji gbimọ pa danu.
MacNelly Vincent, ẹni ọdun mẹtadinlọgbọn ati Gilizibe Taldord, ẹni ọdun mẹrindinlọgbọ, ti wọn ti n pe ni iroyin fi to wa leti wi pe wọn yinbọn pa Abbas lọjọ kejilelogun, oṣu yii.
No comments:
Post a Comment