Kayeefi nla lọrọ naa ṣi n jẹ patapata fun gbogbo awọn ololufẹ gbajugbaja oṣerebinrin nni, Clarion Chukwurah Abiọla lori fọto ihoho rẹ to gbe jade laipẹ yii.
Clarion Chukwurah Abiọla lo gbe fọto ihoho ara rẹ sita lati fi kanminu lori ọrọ iṣoro to n dojukọ orilẹ-ede Naijiria.
Ori ikanni ayelujara ti Instagiramu lo gbe awọn fọto naa si, to si tun jẹ ko ye gbogbo aye wi pe oun ko gbe igbesẹ ọhun lai ni itọni Ẹmi Mimọ.
No comments:
Post a Comment