Dimeji Bankọle, olori ile igbimọ aṣoju-ṣofin tẹlẹri lorilẹ-ede yii lo ti ṣe abẹwo ọdun si Alake ilẹ Ẹgba, Ọba Michael Adedọtun Arẹmu Gbadebọ ni aafin rẹ to wa ni Ake, Abẹokuta, ipinlẹ Ogun.
Ọjọ keji ọdun Ileya to kọja yii, iyẹn ana, Wẹsidee ni Dimeji kọwọ rin pẹlu awọn alatilẹyin rẹ lọ ki kabiyesi.
Diẹ ree lara fọto abẹwo naa:
No comments:
Post a Comment