Ki i ṣe iroyin tuntun mọ pe Ọọni Ile-Ifẹ, Alayeluwa, Ọba Adeyẹye Ẹnitan Ogunwusi ti gbe igbimọ ẹlẹni mejidinlọgbọn kalẹ lati gbe ọrọ Oloye Sunday Adeyẹmọ, Igboho yẹwo, ki wọn si le wa iyanju si i.
Igbimọ naa la gbọ pe agba ati alẹnulọrọ nilẹ Yoruba ni gbogbo wọn.
Awọn naa ni: Ọba Oluṣọla Alao, Olugbọn tilu Igbọn; Sẹnetọ Biọdun Olujimi; Toyin Saraki; Ṣẹgun Awolọwọ; Doyin Okupe; Ọtunba Gbenga Daniel; Ọmọọba Oye Oyewumi; Muyiwa Ige; Ọgagun Olu Okunnọwọ; DIG Taiwo Lakanu; Ṣọla Ẹbiṣeni, akọwe ẹgbẹ Afẹnifẹre; Jimi Agbaje; Ṣọla Lawal; Debọla Oluwagbayi; Dupẹ Adelaja; Dele Mọmọdu; Sẹnatọ Tolu Ọdẹbiyi; Ọmọwe Oluṣẹgun Mimiko; Ọmọwe Ṣeun Ọbasanjọ ati Makin Ṣoyinka
Awọn yooku ni: Dele Adeṣina; AIG Tunji Alapinni; Reuben Abati; Ẹniọla Bello; Bimbọ Aṣhiru; Sẹnetọ Tokunbo Ogunbanjọ; Dapọ Adelegan ati Ọjọgbọn Akin Ọṣuntokun.
Awọn yooku ni: Dele Adeṣina; AIG Tunji Alapinni; Reuben Abati; Ẹniọla Bello; Bimbọ Aṣhiru; Sẹnetọ Tokunbo Ogunbanjọ; Dapọ Adelegan ati Ọjọgbọn Akin Ọṣuntokun.
Ọba Oluṣọla Alao, Olugbọn tilu Igbọn |
Sẹnetọ Biọdun Olujimi |
Toyin Saraki |
Ṣẹgun Awolọwọ |
Olohun Aranwon lowo,Adojuti Gbogbo Ota Yoruba
ReplyDelete