E wo àhámọ́ tí wọ́n fi Sunday Igboho pamọ́ sí ní Kútọnu - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, July 22, 2021

E wo àhámọ́ tí wọ́n fi Sunday Igboho pamọ́ sí ní Kútọnu


Ibi ti ẹ n wo yii ni ahamọ ọlọpaa ti wọn pe ni Brigade De Criminel to wa lagbegbe Berlier, lorilẹ-ede olominira Benin, nibi ti wọn fi olori ajijangbara ilẹ Yoruba, Oloye Sunday Adeyẹmọ, Igboho pamọ si.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI