Ẹ wo afárá tó so orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Cameroon papọ̀ tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ parí - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Tuesday, July 27, 2021

Ẹ wo afárá tó so orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Cameroon papọ̀ tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ parí


Afara ti ẹ n wo yii lo so orilẹ-ede Naijiria ati Cameroon papọ. Ilu Calabar, ipinlẹ Cross River lo wa.

Laipẹ yii ni Ọmọwe Babajide Faṣọla, mimisita f'ọrọ iṣẹ ati ilegbe lorilẹ-ede yii ṣa abẹwo si afara oni kilomita kan ataabọ (1.5km).




No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI