Olori ijọ Ridiimu kaakiri agbaye, Pasitọ Enoch Adejare Adeboye ti fi lẹta ibanikẹdun ranṣẹ si iyawo Oloogbe Temitọpẹ Balogun Joshua, oludasilẹ ṣọọṣi Synagogue Church Of All Nations, SCOAN.
Ọjọ kẹwaa lẹyin ti Pasitọ Temitọpẹ Joshua dagbere faye la gbọ pe Pasito Adeboye fi lẹta naa ranṣẹ labẹlẹ si iyawo T.B Joshua lai jẹ ki ẹnikẹ́ni mọ nipa ẹ.
Bẹ o ba gbagbe, ọjọ karùn-ún, oṣu kẹfa, ọdun yii ni T.B Joshua jade laye, ọjọ kẹẹdogun, oṣù kẹfà to kọja ni Baba Adeboye fi lẹta naa ranṣẹ, ti ẹda rẹ si ti tẹ wa lọwọ
No comments:
Post a Comment