Ẹ wo Odion Ighalo, agbabọọlu Super Eagles ati ibeji rẹ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Wednesday, June 16, 2021

Ẹ wo Odion Ighalo, agbabọọlu Super Eagles ati ibeji rẹ


Pupọ awọn ololufẹ ere idaraya, paapaa awọn ololufẹ gbajugbaja agbabọọlu orileede Naijiria nni, Odion Ighalo ni wọn ko mọ pe ibeji ni.

Obinrin ni ibeji Ighalo, to si rẹwa pupọ.

Awọn mejeeji ree pẹlu mama wọn.



No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI