Gomina Abdulrahman Abdulrazaq ti ipinlẹ Kwara ti fi orúkọ àwọn márùn ùn kan to n woye lati fi wọn ṣe kọmiṣanna ranṣẹ s'ile igbimọ aṣofin ipinlẹ naa lati ṣe àgbéyẹ̀wò wọn.
Awọn orukọ naa ni wọnyi:
Deborah Aremu – Irepodun
Banigbe Remilekun Oluwatobi – Isin
Ibrahim Sulyman – Ilorin West
Saba Magret – Edu
No comments:
Post a Comment