Ko ṣẹlẹ ri: Kwara pin ounjẹ ọfẹ f'awọn alaini, paapaa awọn iyalọja - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Friday, May 21, 2021

Ko ṣẹlẹ ri: Kwara pin ounjẹ ọfẹ f'awọn alaini, paapaa awọn iyalọja


Lai ki i ṣe aaiko ọdun, ijọba ipinlẹ Kwara labẹ akoso Gómìnà AbdulRahman AbdulRazaq tun ti pin ounjẹ ọfẹ fun gbogbo àwọn to ku díẹ kaato fun kaakiri ipinlẹ naa.

Gẹgẹ bí a ṣe gbọ, laipẹ yii ni pinpin ounjẹ ọfẹ naa waye, paapaa fun gbogbo àwọn iyalọja ati babalaje kaakiri ọja to wa ni ipinlẹ naa, eyi to mu k'awọn araalu máa ṣe adura gbigbona fun gómìnà wọn.

Diẹ ree lara awọn ounjẹ ti wọn pin naa:











No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI