Ile mi ṣi wa ni tita lati ran Baba Ijẹṣa lọ s'ẹwọn o - Iyabọ Ojo tun pariwo sita - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Wednesday, May 19, 2021

Ile mi ṣi wa ni tita lati ran Baba Ijẹṣa lọ s'ẹwọn o - Iyabọ Ojo tun pariwo sita


Gbajugbaja òṣèré tíátà nni, Iyabọ Ojo ti sọ pe oun ko yi ìpinnu oun pada lati ran Baba Ijẹṣa ti wọn f'ẹsun ifipabanilopọ kan l'oṣu to kọja yii, nitori pe ẹsun ti ko ṣe e f'ọwọ bo ni.

Bẹ o ba gbagbe, ijẹta ti í ṣe Mọnde ni Onidajọ Oluwatoyin Onaghre sọ pe ki wọn fun ọkunrin naa ni beeli digba ti ile ẹjọ yoo bẹrẹ iṣẹ pada.

Bi iroyin naa ṣe jade sita ni Iyabọ Ojo ti gba ori ikanni ayelujara ti Instagiraamu rẹ lọ, nibi to ti n sọ pe ile oun ṣi wa fun títà f'awọn to l'agbara lati ko owo lee.

Fidio naa ree:

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI