Iku ya ju ẹsin lọ, mo mọ pe mo ti ṣẹ - Baba Ijẹṣa bẹbẹ (Fidio) - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, April 29, 2021

Iku ya ju ẹsin lọ, mo mọ pe mo ti ṣẹ - Baba Ijẹṣa bẹbẹ (Fidio)


Gbajugbaja òṣèré tíátà nni, Ọlanrewaju Omiyinka ti ọpọ awọn èèyàn mọ sí Baba Ìjẹ̀ṣà lo ti bẹbẹ pe ki wọn dá aṣọ aṣiri bóun lati ma jẹ ki aṣiri oun tu sita loju araye.

O ni yóò tẹ oun l'ọrun ki wọn jẹ koun pa ara oun dipo ki wọn ti àṣírí oun sita. Bakan naa lo ni awọn nnkan to n ṣẹlẹ soun kì í ṣe oju lasan, o ni o lọwọ ayé ninu.

Awọn ọrọ wọnyi lo sọ ko to di pe wọn fa a le àwọn ọlọpaa ipinlẹ Eko lọwọ l'ọsẹ to kọjá yii.



No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI