Gbajugbaja aworawọ àgbáyé nni tọpọ awọn èèyàn mọ si Baba Egun Aworawọ ti sọ pe awọn àṣírí mẹrindilogun lati di ọlọla, ọlọrọ nile aye yii lo ti wa nilẹ nikawọ oun fun gbogbo awọn to ba wa ninu ìṣòro lati gba itusilẹ.
Laipẹ yii ni Baba Egun Aworawọ sọrọ naa jade, to si loun ṣetan lati tu gbogbo awọn to ba wa ninu igbekun ayé silẹ kuro lọwọ ogun to n jà wọn
Ilu Agbara ni Baba Egun Aworawọ fi ṣe ibùgbé ni Baba Egun House, Doyin Busstop, Off Agbara Lusada Road, ipinlẹ Ogun.
Ninu ọrọ Bàbá Egun Aworawọ lo ti sọ pe:
Ẹ ku ọjọ meji mẹta o gbogbo ẹyin ololufẹ Baba Egun Aworawọ, ṣe alaafia la ba a yin? Gẹgẹ bi e ti ṣe mọ wi pe iwadii aye jẹ emi Baba Egun Aworawọ logun, to si mọmu lookan aya mi. Ẹda to ba fẹẹ jẹ eeyan tabi to fẹẹ ṣe rere nile aye ti a wa yii ko gbọdọ jokoo tẹtẹrẹ, ko kawọ gbera, ko si maa reti awọn nnkan rere ile aye lai dide lati gbe igbesẹ to yẹ. Nitori naa, awọn agba sọ pe ninu igbiyanju ni ẹda ti n ṣe rere laye, to si n ni itẹsiwaju. Irufẹ itẹsiwaju wo lo n wa? Ṣe lati di olowo, ọlọla tabi ọlọrọ nile aye ni tabi lati di alaisiki rẹpẹtẹ? Iru irin ajo yii ko gba ọ laaye lati kawọ gbera, ibikibi ti o ba wa, dide ki o si maa bọ lọdọ emi Baba Egun Aworawọ. Ọpọ eeyan lo ti wa, ti wọn si ti bọ kuro lọwọ ogun aye nipa agbara Olodumare ti wọn n ba pade lọdọ mi, anfaani nla lo ṣi silẹ fun ẹ yii.
Ka to o tẹsiwaju, mo fẹ fi asiko yii rọ gbogbo awọn ololufẹ Baba Egun Aworawo ti wọn ti wa a ṣẹ igi Aje wọn lọdọ wa pe ki wọn ma ṣe gbagbe pe gbogbo ọjọ Mọnde to jẹ ọjọ Aje to ba gbẹyin ninu oṣu ni wọn yoo maa rúbọ Aje wọn ki ẹ le maa ri Aje yin lo titi lai. Gbogbo awọn to ti wa a ṣẹgi Aje lọdọ wa ni Aje ti n ba wọn gbe, ti wọn si ti n jẹrìí lọwọlọwọ. Aje ọla ṣiṣẹ jẹ nnkan to rọrun lati ṣe, ọpọlọpọ lo ro pe ọna lati lowo lọwọ laye yii rọrun, ṣugbọn ko ri bẹẹ, wọn ni lati gbe igbesẹ. O ni awọn ọna tàwọn baba nla wa tọ laye atijọ, ti aye fi dun fun wọn nigba ti wọn, awọn àṣírí ọna yii lo wa lọdọ Baba Egun Aworawọ. Ibikibi ti o ba wa, ti o ti n ka iwe yii, maa bọ bayii.
A ṣẹṣẹ de lati ibi iwadii oṣù mẹfa gbako to tun lagbara kan nipa aye yii ni, anfaani ree lati gba gbogbo ikolọ yin pada.
Mo fẹ ki ẹ mọ daju pe ile aye ti a wa yii jẹ ile aye to ṣokunkun si ẹda, ṣugbọn ti Ọlọrun tan imọlẹ rẹ fun awọn eeyan bi i Baba Egun Aworawọ lati fi wa ojutuu tabi ọna abayọ si iṣoro eda laye. Oṣo lo n yọ ẹ lẹnu ni tabi ajẹ, idile iya tabi ti baba ni wọn ti n pọn ẹ loju ni, tete maa bọ lọdọ emi Baba Egun Aworawọ bayii lati mọ ibi to ku si lori ọrọ aye rẹ, ki o si le mo igbesẹ to maa gbe.
Gbogbo ọdun to kọja lo fi kawọ gbera, bẹẹ si ree, ọdun yii naa lo tun n pari lọ diẹdiẹ yii, njẹ o mọ pe ayanmọ rẹ wa lọwọ rẹ, igbesẹ ti o ba si gbe lo maa sọ ibi ti o fẹẹ de laye, oorun to wa loke yii ṣi to lati gbẹ aṣọ fun awọn ọlọgbọn eeyan, tete wa a pọn omi silẹ de ongbẹ. Gẹgẹ bi ẹ ti ṣe mọ pe Ọlọrun yọnda ewe ati egbo fun ilẹ Egun fun amulo agbara, awọn àṣírí agbara to lagbara si wa lọwọ emi Baba Egun Aworawọ.
Ninu iwadii ti a ṣe la tun ti ni Àṣírí Mẹrindinlogun lati sọ emẹ di ohun yoowu to o fẹ da laye, maa bo lọdọ wa lonii. Bi ẹ ba n bọ wa si ọfiisi Baba Egun Aworawọ, ẹ ma gbagbe lati mu owo fọọmu ẹgbẹrun meji (N2,000) naira dani. Baba Egun Aworawọ tun ti wa lori Wasaapu bayii pẹlu nọmba yii 09022671569 lati jọ sọrọ papọ.
Gbogbo ẹyin ti ẹ n beere fun awọn akanṣe iṣẹ Baba Egun Aworawọ, a n fi asiko yii sọ fun un yin pe awọn iṣẹ tuntun mi in ti wa nilẹ bayii. Fun anfaani ẹyin ti ẹ n beere fun Agbo Iṣẹmbaye to n ṣiṣẹ fun 'Wẹ Egun, Wẹ Epe', o ti wa nile lọpọ yanturu. Omi Itaja Ajẹbiidan, Miracle Water naa tun ti wa nilẹ fun ilọsiwaju okoowo yin naa wa nilẹ. Stop Evil, Favour Perfume, Holy Ghost Fire Oil, Shower of Blessing Perfume, Ose to n we abilu kuro lara naa ti wa nilẹ. Fun alaye lẹkunrẹrẹ lori awon oja wa, e pe 08106412911. Aye a dun fun gbogbo wa o.
Lara awọn ẹri tàwọn to ti dan Baba Egun Aworawọ wo niwonyii:
Ọdún mẹ́tàdínlógún ree ti nnkan ti dojuru fun mi, oṣù kejila ọdún to kọja ni mo gburo nipa Baba Egun Aworawọ. Latigba ti mo ti de ọdọ wọn lọrọ aye mi ti yi pada, gbogbo awọn ti wọn ko fẹẹ ri mi tẹlẹ ni wọn ti n pe mi fun iranlọwọ. - Bọwale Aderọgba, Òṣogbo.
Latigba ti mo ti ṣẹgi Aje Ọla lọdọ Baba Egun Aworawọ l'oṣu kinni ọdún yii ni Aje ti fi ile mi ṣe ibugbe. Mo n tọrọ jẹ ni tẹlẹ ni, ṣugbọn mo ti di ẹni to n fun awọn eeyan lowo. - Johnson Olanrewaju, Eko.
Ẹyin naa le dan Baba Egun Aworawọ wo lónìí nipa pipe sori èyíkéyìí ninu awọn ẹrọ ibanisọrọ yìí: 07038302541, 07040508855, 08165703400, 08106412911
No comments:
Post a Comment