GBAJUMỌ ADAJỌ KU LOJIJI - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Wednesday, February 17, 2021

GBAJUMỌ ADAJỌ KU LOJIJI


Ọkan lara awọn gbajugbaja adajọ lorilẹ-ede yii, Onidajọ Morrison Ighodalo t'ipinlẹ Edo ti jade laye.
 
Ipo kẹta ni Onidajọ Ighodalo wa laaarin awọn adajọ mọkanlelọgbọn  ti oṣuwọn wọn gbe pẹli daadaa.
 
Bi iroyin iku ẹ ṣe jade sita la gbọ pe awọn adajọ n'ipinlẹ Edo ti sun gbogbo igbẹjọ to wa n'iwaju wọn s'iwaju lati fi bu ọla ati ẹyẹ fun un. 
 
Akọwe ipolongo ẹgbẹ awọn amofin n'ipinlẹ Edo, Ogaga Emoghwanre to gbe iroyin naa sita sọ pe gbogbo ẹgbẹ amofin patapata lo wa ninu ibanujẹ oloogbe naa, tori pe nnkan t'awọn ko lero tẹlẹ ni.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI