Ipinlẹ Kwara ti ni kọmiṣanna ọlọpaa tuntun bayii, Mohammed Lawal Bagega lorukọ ẹ.
Mohammed Bagega lo gba ipo naa lọwọ Kayọde Ẹgbẹtokun to jẹ kọmiṣanna ọlọpaa tẹlẹ n'ipinlẹ naa.
Gẹgẹ ba a ṣe gbọ, ọmọ ijọba ibilẹ Anka nípinlẹ Zamfara ni Bagega, to si kẹkọọ gboye pẹlu imọ ọrọ oṣelu, iyẹn Political Science. Ipinlẹ Plateau lo ti sin orilẹ-ede baba rẹ, iyẹn agunbanirọ.
Ọjọ kinni oṣu kẹta ọdun 1990 ni Bagega wọ iṣẹ ọlọpaa
No comments:
Post a Comment