IṢẸ AGBẸ: GOMINA ABIỌDUN GBA AAMI ẸYẸ KORIYA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, December 3, 2020

IṢẸ AGBẸ: GOMINA ABIỌDUN GBA AAMI ẸYẸ KORIYA


Irọlẹ ana ti i ṣe Ọjọru, iyẹn Wẹsidee ni Gomina Dapọ Abiọdun tun gba aami ẹyẹ tuntun lati ọdọ awọn alaṣẹ ileeṣẹ kan to n ri sọrọ iṣẹ agbẹ ati ọgbin lorilẹ-ede yii, iyẹn Nigeria Agriculturae Awards.
 
Ohun ta a gbọ ni pe aami ẹyẹ naa ni wọn sọ pe Gomina Abiọdun lo gba ipo kinni l'ọdun 2020 ninu awọn gomina orilẹ-ede yii to mu iṣẹ agbẹ lokunkundun.
 
Ilu Abuja ni eto naa ti waye, diẹ si ree lara awọn fọto bi eto naa ṣe lọ.
 
 
 
 
 
 
 
 

 
 
 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI