Titi di àsìkò tí a kọ ìròyìn yìí tán ni kò ti í sẹni tó lè sọ pàtó nípa àwọn tó pá baálé ilé kan tá a kò ti í mọ orúkọ ẹ dànù sínú mọto ẹ.
Òpópónà Evo tó wa ni GRA, ìlú Port Harcourt, ìpínlẹ̀ Rivers là gbọ́ pé ìṣẹ̀lẹ̀ burúkú tó ṣeni ni kayeefi náà tí wáyé lọ́jọ́ Tọside ijẹta.
Àwọn ọlọpaa là gbọ́ pé wọn padà gbé òkú ọkùnrin náà lọ sí mọṣuari.
No comments:
Post a Comment