WAHALA MI-IN TUN N BỌ NI NAIJIRIA! ILEEṢẸ ELEPO FẸẸ DA IṢẸ SILẸ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, November 9, 2020

WAHALA MI-IN TUN N BỌ NI NAIJIRIA! ILEEṢẸ ELEPO FẸẸ DA IṢẸ SILẸ


Afaimọ ni ki i wahala mi in ma tun bẹ silẹ kaakiri orilẹ-ede Naijiria pẹlu b'awọn ileeṣẹ elepo rọbi ṣe tun da iṣẹ silẹ kaakiri bayii.
 
Gẹgẹ bi a ṣe gbọ, ẹgbẹ awọn elepo, iyẹn Petroleum and Natural Gas Senior Staff Association of Nigeria, PENGASSAN ni wọn kọ iwe s'awọn ileeṣẹ elepo kaakiri wi pe ki wọn da iṣẹ silẹ.
 
Akọwe ẹgbẹ naa, Lumumba Okugbawa ninu lẹta to gbe jade lanaa ti i ṣe ọjọ Aiku-Sannde lo ti sọ pe ijọba apapọ ko san awọn owo to jẹ wọn, idi ree to fi ni afi k'awọn naa wa ọna abayọ.
 
Lẹta naa ree:
 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI