Gbọngan àṣà ipinlẹ Ogun, ìyẹn June 12 Cultural Centre to wá ní Kutọ n'ilu Abẹ́òkúta kò gbà èrò bí ẹ ṣe ń ka ìròyìn yìí.
Minisita f'ọrọ àṣà, Iroyin àti irin àjò afẹ́ lorilẹ-ede Nàìjíríà, Alaaji Lai Mohammed náà wá nibẹ pẹ̀lú láti yẹ ayẹyẹ aṣọ ilẹ̀ Ẹ̀gbá, ìyẹn Àdìrẹ́ sí.
Káàkiri àgbáyé ni wọn ti ń wọ aṣọ Àdìrẹ́, táwọn èèyàn tún ń pè ní Kampala torí pé ó gbayì, ó sì gbajúmọ̀ káàkiri àgbáyé.
No comments:
Post a Comment