LẸYIN ROGBODIYAN IWỌDE IFẸHONU HAN #ENDSARS ATI WAHALA LEKKI, ỌGA ỌLỌPAA ṢABẸWO S'ILU EKO - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Wednesday, November 4, 2020

LẸYIN ROGBODIYAN IWỌDE IFẸHONU HAN #ENDSARS ATI WAHALA LEKKI, ỌGA ỌLỌPAA ṢABẸWO S'ILU EKO


Ọga ọlọpaa lorilẹede Naijiria, Muhammed Adamu ni o ṣeni laanu wi pe idi ti awọn ọdọ fi ṣe ifẹhọnuhan Endsars ko kẹsẹjari.


Ọga ọlọpaa lorilẹede Naijiria, Muhammed Adamu lo fi ero rẹ han lori bẹẹ lasiko to ṣe abẹwo si ipinlẹ Eko.


O ni biba ohun ini jẹ lasiko ifẹhọnuhan Endsars ti awọn janduku gba mọ wọn lọwọ lodi si ofin.


Nitori naa o rọ awọn ọdọ lati ma a tẹle ofin to de ifẹhọnuhan ki awọn janduku ma ba a jagba lọwọ wọn.


Lati: BBC

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI