ILE-ẸJỌ KOTẸMILỌRUN DA ỌNỌREBU ADAM RUFAI LARE - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Tuesday, November 24, 2020

ILE-ẸJỌ KOTẸMILỌRUN DA ỌNỌREBU ADAM RUFAI LARE


Ọjọ Aje-Mọnde ana ni ile ẹjọ kotẹmilọrun orilẹ-ede yii, ẹka t'ipinlẹ Kwara to wa n'ilu Ilọrin da Ọnọerbu Adam Rufai ti ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress lare lori idibo to waye.
 
Lati ọjọ kẹrinla oṣu kẹta ọdun yii la gbọ pe awọn ọmọ égbẹ oṣelu Peoples Democratic Party, PDP ati All Progressives COngress, APC ti n ja ija ajaku-akata lori ipo naa, ti wọn si gba ile ẹjọ lọ lati yanju ẹ fun wọn.
 
Ninu atẹjade ti ẹgbẹ oṣelu APC gbe jade lonii lẹyin abajade idajọ ile ẹjọ naa ni wọn ti sọ pe oriire nla lo wọle tọ wọn tori pe ile ẹjọ da wọn lare lọna ofin.
 
Bẹẹ ni wọn tun l'awọn ba Gomina ipinlẹ naa, Abdulrahman Abdulrazaq yọ wi pe ẹjọ naa yẹ wọn.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI