Igbakeji gomina ipinlẹ Kwara, Ọgbẹni Kayọde Alabi ti sọ pe ijọba ipinlẹ naa n gbiyanju gbogbo agbara ati akitiyan rẹ lati ri i pe idagbasoke alailẹgbẹ n b'awọn agbegbe to wa kaakiri ipinlẹ naa.
Kayọde Alabi lo sọ eyi di mimọ nibi eto apapọ nni ti wọn pe ni National Community Development, eyi to waye ninu ṣọọṣi ECWA to wa nilu Ilọrin lọsẹ to kọja yii.
O ni ohun iwuri b'awọn agbegbe ati igberiko ilu ba n ni ilọsiwaju, to si lo jẹ nnkan pataki ninu idagbasoke eto ọrọ aje ilu.
No comments:
Post a Comment