Lónìí ọjọ́ Iṣẹgun-Tusidee ni Gómìnà ipinlẹ Ogun, Ọmọba Dapọ Abiọdun búra fún gbogbo àwọn igbimọ alabaṣiṣẹpọ rẹ tuntun.
Ọsẹ to lọ lọhun ni Gómìnà Abiọdun kéde àwọn igbimọ náà láti di onírúurú eka ètò iṣejọba rẹ mú.
Nibẹ lo tí gba àwọn igbimọ náà lamọran láti rí í pé wọn ṣiṣẹ takuntakun fún igbelarugẹ ipinlẹ náà.
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ń bọ̀ laipẹ.
No comments:
Post a Comment