Pupọ awọn eeyan kaakiri agbaye ni wọn ti n ro pe isin ko ni i waye lonii ọjọ Sannde ninu ṣọọṣi ṣẹlẹ ti Genesis Global to jẹ ti Wolii Israel Ọladele Ogundipẹ lori awọn awuyewuye kan to n lọ nigboro nipa ẹ.
Ṣugbọn ọrọ ko ri bẹẹ rara tori pe Ọlọrun ju ẹda lọ l'awọn ọmọ ijọ rẹ fi ṣe, ti wọn si dupẹ lọwọ Ọlọrun pe o ṣi n jọba lori itẹ.
Diẹ ree lara bi isin ologo ṣe lọ ninu ijọ naa.
No comments:
Post a Comment