Titi di asiko ta a pari iroyin yii l'awọn ọmọ ipinlẹ Kwara fi n jo, ti wọn n yọ lori owo ti wọn ṣẹṣẹ gba lọwọ ijọba apapọ, gẹgẹ bi owo alokeṣan (allocation) fun oṣu kọkanla ọdun yii.
Biliọnu mẹta le diẹ (3.4b) naira lowo naa jẹ, ti wọn si ni biliọnu meji le (N2.2b) naira leyi to jẹ t'ijọba ibilẹ ninu ẹ.
Kọmiṣanna fun eto iṣuna, Florence Ọlasumbọ lo sọrọ naa jade sita wi pe diẹ lowo naa fi din si eyi t'awọn gba l'oṣe kẹwaa to kọja.
O ni N364,521,954:41 naira l'awọn gba loṣu yii, to si ni biliọnu mẹrin din diẹ (N3.7b) naira l'awọn gba loṣu kẹwaa
Nigba to n ṣapejuwe awọn ibi towo naa n lọ, o ni
Statutory Revenue Allocation (SRA) of N1,793,570,467:35 (net);
Value Added tax (VAT) of N1,182,283,927:63;
Forex Equilibrium of N40,341,748:68;
Excess Crude of N392,895,753:25;
Excess Bank Charges of N6,280,636:40; ati
(Part Loan) Deductions of N310,656,652:68.
Bẹẹ lo sọ pe owo t'awọn ijọba ibilẹ mẹrindinlogun naa tun ja walẹ, to si ni N2,245,856,487:93 ni wọn gba, eyi to ni owo ti wọn gba lóṣe to kọja jẹ N2.4bn.
No comments:
Post a Comment