OWÓ ÌṢÒWỌ: ÌDÙNNÚ TÚN ṢUBÚ LU AYỌ̀ AWỌN ARÁÀLÚ - IROYIN AWIKONKO

Saturday, October 31, 2020

demo-image

OWÓ ÌṢÒWỌ: ÌDÙNNÚ TÚN ṢUBÚ LU AYỌ̀ AWỌN ARÁÀLÚ

IMG_ORG_1604070141564

Bí wọn ba fún ẹṣin nínú àwọn ọmọ ipinlẹ Kwara lásìkò yìí, kódà, onitọhun kò ní í kọsẹ̀ rárá lórí bí wọn ṣe ń jẹ àǹfààní owó idokowo tijọba fi ń rán àwọn aráàlú lọ́wọ́, èyí tí wọn pé ni Owó Ìṣòwò. 

Lati bí oṣù mélòó kan sẹ́yìn n'ijọba Gómìnà AbdulRahman AbdulRazaq tí bẹ̀rẹ̀ si í pín owó fáwọn aráàlú, pàápàá àwọn tó ń jà ọjà kéékèèké. 

Àwọn tó lè ní ẹgbẹ̀rún mọkanlelogun {21,623} là gbọ pé wọn yóò jẹ àǹfààní náà lai ni ojuṣaaju kankan nínú. 

Díẹ̀ tún rèé lára àwọn aráàlú tí wọn tún ṣẹ̀ṣẹ̀ je àǹfààní Owó Ìṣòwò náà n'ijọba ìbílẹ̀ Moro.

IMG_ORG_1604070162569

IMG_ORG_1604070162703

IMG_ORG_1604070162358


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI

Contact Form

Name

Email *

Message *