Obrigado Nike Football ti ṣe bàtà tuntun fún gbajugbaja agbabọọlu àgbáyé nnì, Cristiano Ronaldo, ọmọ orílẹ̀ èdè Portugal.
Ronaldo to ń gba bọọlu fún ẹgbẹ́ agbabọọlu Juventus lo gbé ìròyìn náà síta fúnra rẹ lànà án, tó sì lòun tètè ń retí ọjọ́ tòun yóò lo bàtà náà.
Nínú ọ̀rọ̀ rẹ síwájú sí í lo tí lòun fẹẹ fi bàtà náà ṣajọyọ iṣẹ bọọlu tòun yàn láàyò àti oriire toun tí ṣe nìdí ẹ.
No comments:
Post a Comment